Deutarónómì 23:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹrú kan bá ti gba ààbò lọ́dọ̀ rẹ, má ṣe fi lé ọ̀gá rẹ̀ lọ́wọ́.

Deutarónómì 23

Deutarónómì 23:12-25