Deutarónómì 22:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má se fi ohunkóhun ṣe ọmọbìnrin náà; kò ṣẹ ẹ̀ṣẹ̀ tí ó tọ́ sí ikú. Ẹjọ́ yìí rí bí i ti ẹnìkan tí a gbámú tí ó pa aládùúgbò rẹ̀.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:17-30