Deutarónómì 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Baba obìnrin náà yóò wí fún àwọn àgbààgbà, pé “Mo fi ọmọbìnrin mi fún ọkùnrin yìí láti fẹ́ níyàwó, ṣùgbọ́n ó kórìíra rẹ̀.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:10-18