Deutarónómì 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí o sì sọ̀rọ̀ ìbàjẹ́ sì i tí o sì fún un ní orúkọ búburú, wí pé, “Mo fẹ́ obìnrin yìí, ṣùgbọ́n nígbà tí mo sún mọ́ ọn. Èmi kò rí àmì ìbálé e rẹ̀.”

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:12-21