Deutarónómì 21:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí inú rẹ̀ kò bá sì dùn si i, jẹ́ kí ó lọ sí ibikíbi tí ó bá fẹ́. O kò gbọdọ̀ tà á tàbí lò ó bí ẹrú, lẹ́yìn ìgbà tí o ti dójú tì í.

Deutarónómì 21

Deutarónómì 21:10-23