Deutarónómì 20:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí wọ́n bá gbà tí wọ́n sì sí ìlẹ̀kùn, gbogbo àwọn tó wà níbẹ̀ yóò máa jẹ́ olùsìn fún ọ, wọn ó sì máa sìn ọ́.

Deutarónómì 20

Deutarónómì 20:5-13