Deutarónómì 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(A ka ilẹ̀ yìí sí ilẹ̀ àwọn Réfáímù, tí wọ́n ti gbé níbẹ̀ rí, ṣùgbọ́n àwọn ará Ámónì ń pè wọ́n ní Sámúsúmímù.

Deutarónómì 2

Deutarónómì 2:12-27