Deutarónómì 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe fi àánú hàn, ẹ̀mí fún ẹ̀mi, ojú fún ojú, eyín fún eyín, apá fún apá, ẹṣẹ̀ fún ẹṣẹ̀.

Deutarónómì 19

Deutarónómì 19:16-21