Deutarónómì 19:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò ya ìlú mẹ́ta sọ́tọ̀ fún ara à rẹ láàrin ilẹ̀ rẹ tí Olúwa Ọlọ́run fún ọ láti ni.

Deutarónómì 19

Deutarónómì 19:1-5