Deutarónómì 19:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn adájọ́ gbọ́dọ̀ ṣe ìwádìí fínnífínní bí ẹ̀rí bá sì jẹ́ irọ́, tí ó fi ẹ̀rí èké sun arákùnrin rẹ̀,

Deutarónómì 19

Deutarónómì 19:15-21