Deutarónómì 19:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹlẹ́rìí kan ṣoṣo kò tó láti dájọ́ ọkùnrin kan tí o fi ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ yóò wù kí ó lè ṣẹ̀ lẹ́bi. A ó fi ìdí ọ̀rọ̀ múlẹ̀ láti orí ẹ̀rí ẹni méjì tàbí mẹ́ta.

Deutarónómì 19

Deutarónómì 19:13-19