Deutarónómì 19:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má ṣe ṣàánú fún un. O ní láti fọ ẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ kúrò ni Isírẹ́lì, kí ó báà lè dára fún ọ.

Deutarónómì 19

Deutarónómì 19:4-17