Deutarónómì 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnikẹ́ni tí kò bá sì tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ mi tí wòlíì náà yóò sọ ní orúkọ mi, èmi fúnra à mi yóò sì béèrè lọ́wọ́ ọ rẹ̀.

Deutarónómì 18

Deutarónómì 18:12-22