Deutarónómì 18:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò gbé wòlíì kan dìde gẹ́gẹ́ bí èmi láàrin àwọn arákùnrin rẹ. Tìrẹ ni kí o gbọ́.

Deutarónómì 18

Deutarónómì 18:13-22