Deutarónómì 17:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹjọ́ bá wá sí ilé ẹjọ́ ọ yín tí ó nira jù láti dá: yálà ìtàjẹ̀sílẹ̀ ni, ọ̀ràn dídá tàbí ìkanni-lábùkù: Ẹ mú wọn lọ sí ibi tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò yàn.

Deutarónómì 17

Deutarónómì 17:7-18