Deutarónómì 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ mú ọkùnrin tàbí obìnrin tí ó ti ṣe ibi yìí wá sí ẹnu ọ̀nà ibodè ìlú u yín, kí ẹ sọ ọ́ ní òkúta pa.

Deutarónómì 17

Deutarónómì 17:1-9