Deutarónómì 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ṣun ún kí ẹ sì jẹ ẹ́ ní ibi tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò yàn. Ní àárọ̀, kí ẹ padà sí àgọ́ ọ yín.

Deutarónómì 16

Deutarónómì 16:3-17