Deutarónómì 16:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ yan àwọn adájọ́ àti àwọn olóyè fún ẹ̀yà a yín kọ̀ọ̀kan, ní gbogbo ìlú tí Olúwa Ọlọ́run yín yóò fún un yín, wọ́n sì gbọdọ̀ máa fi òtítọ́ ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn.

Deutarónómì 16

Deutarónómì 16:15-22