Deutarónómì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ rántí pé ẹ ti jẹ́ ẹrú ní Éjíbítì rí, nítorí náà ẹ tẹ̀lé àwọn ìlànà wọ̀nyí dáradára.

Deutarónómì 16

Deutarónómì 16:7-16