Deutarónómì 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí talákà kan bá wà láàrin àwọn arákùnrin yín ní èyíkèyí àwọn ìlú, ilẹ̀ náà tí Olúwa yín yóò fún un yín. Ẹ má ṣe se àìláànú bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má ṣe háwọ́ sí arákùnrin yín tí ó jẹ́ tálákà.

Deutarónómì 15

Deutarónómì 15:1-16