Deutarónómì 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹran ọ̀ṣìn kan bá ní àbùkù: bóyá ó yarọ, tàbí fọ́jú, tàbí tí ó ní èyíkèyìí àbùkù tó burú. Ẹ kò gbọdọ̀ fi rúbọ sí Olúwa Ọlọ́run yín.

Deutarónómì 15

Deutarónómì 15:12-23