Deutarónómì 15:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ìwọ kí ó mú ìlu kan lu etí rẹ̀ mọ́ ara ìlẹ̀kùn, yóò sì di ẹrú rẹ láéláé. Bẹ́ẹ̀ náà ni kí o ṣe sí ìránṣẹ́ ẹrúbìnrin rẹ.

Deutarónómì 15

Deutarónómì 15:14-23