Deutarónómì 15:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Hébérù ara yín kan, yálà ọkùnrin tàbí obìnrin bá ta ara rẹ̀ fún ọ, tí ó sì sìn ọ́ fún ọdún mẹ́fà. Ní ọdún kéje, jẹ́ kí ó di òmìnira.

Deutarónómì 15

Deutarónómì 15:8-14