Deutarónómì 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú gbogbo ẹ̀dá alààyè tí ń gbé inú omi, ẹ lè jẹ èyíkéyí tí ó ní lẹbẹ àti ìpẹ́.

Deutarónómì 14

Deutarónómì 14:3-15