Deutarónómì 14:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fi owó náà ra ohunkóhun tí o bá fẹ́, màlúù, àgùntàn, wáìnì, tàbí ọtí líle, tàbí ohunkóhun tí o bá fẹ́. Kí ìwọ àti ìdílé rẹ sì jẹ ẹ́ níwájú Olúwa níbẹ̀ kí ẹ sì máa yọ̀.

Deutarónómì 14

Deutarónómì 14:16-28