Deutarónómì 14:11-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Ẹ lè jẹ ẹyẹ tí ó bá mọ́.

12. Ṣùgbọ́n ìwọ̀nyí ní ẹ kò gbọdọ̀ jẹ: idì, igún, àkàlà,

13. onírúurú àṣá àti àṣá alátagbà,

14. onírúurú ẹyẹ ìwò,

15. ògòǹgò, òyo, pẹ́pẹ́yẹdò àti onírúurú àwòdì,

Deutarónómì 14