Deutarónómì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níbẹ̀ ni kí ẹ mú ọrẹ síṣun àti ẹbọ yín wá, ìdámẹ́wàá yín àti ọrẹ àkànṣe, àwọn ẹ̀jẹ́ yín, ọrẹ àtinúwá yín, àti àwọn àkọ́bí gbogbo màlúù yín àti ewúrẹ́ ẹ yín.

Deutarónómì 12

Deutarónómì 12:1-7