Deutarónómì 12:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa Ọlọ́run yín bá ti fẹ́ agbègbè e yín bí ó ti ṣe ìlérí, fún un yín, tí ẹ sì wí pé, àwa yóò jẹ ẹran, nítorí tí ọkàn wa fẹ́ jẹran. Ẹ jẹ ẹran náà bí ẹ tí fẹ́.

Deutarónómì 12

Deutarónómì 12:19-23