Deutarónómì 12:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ibi tí Olúwa yóò yàn láàrin àwọn ẹ̀yà a yín nìkan ni kí ẹ ti máa rú ẹbọ yín, kí ẹ sì máa kíyèsí ohun gbogbo tí mo pàṣẹ fún un yín níbẹ̀.

Deutarónómì 12

Deutarónómì 12:5-20