Deutarónómì 11:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ìbùkún ni, bí ẹ bá pa òfin Olúwa Ọlọ́run yín, tí mo ń fún un yín lónìí mọ́.

Deutarónómì 11

Deutarónómì 11:25-32