Deutarónómì 11:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ọjọ́ ọ yín àti ti àwọn ọmọ yín lè pọ̀ ní ilẹ̀ tí Olúwa ti búra láti fifún àwọn baba ńlá a yín, ní ìwọ̀n ìgbà tí ọ̀run wà lókè tí ayé sì ń bẹ ní ìṣàlẹ̀.

Deutarónómì 11

Deutarónómì 11:18-23