Deutarónómì 11:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ṣọ́ra, kí a má bàá tàn yín jẹ láti yípadà kí ẹ sì sin Ọlọ́run mìíràn àti láti máa foríbalẹ̀ fún wọn.

Deutarónómì 11

Deutarónómì 11:12-24