Deutarónómì 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ilẹ̀ tí ẹ̀ ń wọ̀ lọ láti gbà kò rí bí ilẹ̀ Éjíbítì, níbi tí ẹ ti wá, níbi tó jẹ́ wí pé ẹṣẹ̀ yín ni ẹ fi ń rìn lọ bominrin irúgbìn tí ẹ gbìn bí oko ẹ̀fọ́.

Deutarónómì 11

Deutarónómì 11:4-13