Deutarónómì 10:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì kan àpótí náà pẹ̀lú igi kaṣíà, mo sì gbẹ́ síléètì òkúta méjì náà jáde bí i ti ìṣáájú. Mo sì gòkè lọ pẹ̀lú síléètì méjèèjì lọ́wọ́ mí.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:1-9