Deutarónómì 10:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àádọ́rin (70) péré ni àwọn baba ńlá a yín tí ó sọ̀kalẹ̀ lọ sí Éjíbítì, ṣùgbọ́n Olúwa Ọlọ́run yín ti mú un yín pọ̀ síi ní iye bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:12-22