Deutarónómì 10:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé Olúwa Ọlọ́run yín ni ó ni ọ̀run àní àwọn ọ̀run tó ga ju ayé àti ohun gbogbo tí ó wà nínú rẹ̀.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:10-15