Deutarónómì 1:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn èwe yín tí ẹ ṣọ pé wọn yóò kó lẹ́rú. Àwọn ọmọ yín tí ko tí ì mọ rere yàtọ̀ sí búburú ni yóò wọ ilẹ̀ náà.

Deutarónómì 1

Deutarónómì 1:34-46