Deutarónómì 1:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò ṣe Kálẹ́bù ọmọ Jéfúnì. Òun ni yóò wọ̀ ọ́. Èmi yóò sì fún òun àti àwọn ìran rẹ̀ ní ilẹ̀ náà tí ó ti fi ẹṣẹ̀ rẹ̀ tẹ̀; torí pé ó fi gbogbo ọkàn rẹ̀ tẹ̀lé Olúwa.”

Deutarónómì 1

Deutarónómì 1:31-41