Dáníẹ́lì 9:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áà! Olúwa, àwa àti àwọn ọba wa, àwọn ọmọ aládé, àti àwọn baba wa, ìtìjú dé bá wa nítorí àwa ti dẹ́ṣẹ̀ sí ọ.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:1-18