Dáníẹ́lì 9:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kò fetí sí àwọn wòlíì ìránṣẹ́ rẹ, ẹni tí ó sọ̀rọ̀ ní orúkọ rẹ sí àwọn ọba wa, àwọn ọmọ aládé àti àwọn baba wa, àti sí gbogbo ènìyàn ilẹ̀ náà.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:1-12