Dáníẹ́lì 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tẹ́ etí rẹ sílẹ̀, Ọlọ́run, kí o gbọ́; ya ojú ù rẹ sílẹ̀, kí o sì wo ìdahoro ìlú tí a ń fi orúkọ rẹ pè. Àwa kò gbé ẹ̀bẹ̀ wa kalẹ̀ níwájú u rẹ nítorí pé a jẹ́ olódodo, bí kò ṣe nítorí àánú ńlá rẹ.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:11-24