Dáníẹ́lì 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ìsinsin yìí, Olúwa Ọlọ́run wa, ẹni tí ó mú àwọn ènìyàn rẹ̀ jáde láti ilẹ̀ Éjíbítì wá, pẹ̀lú ọwọ́ agbára, tí ó fún ara rẹ̀ ní orúkọ tí ó wà títí di òní, a ti ṣẹ̀, a sì ti ṣe búrurú.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:14-23