Dáníẹ́lì 9:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa kò gbọ́ràn sí Olúwa Ọlọ́run wa, a kò sì pa àwọn òfin rẹ mọ́, èyí tí ó fún wa nípasẹ̀ àwọn wòlíì ìránṣẹ́ rẹ̀.

Dáníẹ́lì 9

Dáníẹ́lì 9:7-17