Dáníẹ́lì 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú ìran náà, mo rí ara mi nínú ilé ìṣọ́ ní Súsáni ní agbègbè ìjọba Élámù: nínú ìran náà mo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ odò Úláì.

Dáníẹ́lì 8

Dáníẹ́lì 8:1-10