Dáníẹ́lì 8:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sọ fún mi pé, “Yóò gbà tó ẹgbọ̀kànlá lé lọ́gọ́rùn-ún (2,300) alẹ́ àti òwúrọ̀; lẹ́yìn náà ni a ó tún ibi mímọ́ yà sí mímọ́.”

Dáníẹ́lì 8

Dáníẹ́lì 8:5-21