Dáníẹ́lì 7:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A sì gba ìjọba lọ́wọ́ àwọn ẹranko yóòkù, ṣùgbọ́n a fún wọn láàyè láti wà fún ìgbà díẹ̀.

Dáníẹ́lì 7

Dáníẹ́lì 7:3-20