Dáníẹ́lì 6:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsin yìí, ìwọ ọba, gbé òfin yìí jáde, kí o sì kọ ọ́ sínú ìwé kí a má ba à yí i padà ní ìbámu pẹ̀lú òfin àwọn Médíánì àti Páṣíà, èyí tí kò ní le è parẹ́.”

Dáníẹ́lì 6

Dáníẹ́lì 6:4-18