Dáníẹ́lì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ọba gbọ́ èyí, inú un rẹ̀ bàjẹ́ gidigidi; ó pinnu láti kó Dáníẹ́lì yọ, títí òòrùn fi rọ̀, ó sa gbogbo ipá a rẹ̀ láti gba Dáníẹ́lì sílẹ̀.

Dáníẹ́lì 6

Dáníẹ́lì 6:8-19