Dáníẹ́lì 5:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ojú ọba sì yí padà, ẹ̀rù sì bàá, tó bẹ́ẹ̀ tí orúnkún ẹṣẹ̀ rẹ̀ méjèèjì rẹ̀ fi ń gbá ara wọn.

Dáníẹ́lì 5

Dáníẹ́lì 5:1-11