Dáníẹ́lì 4:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo lá àlá kan èyí tí ó bà mí lẹ́rù. Nígbà tí mo wà lórí ibùṣùn mi, ìran tí ó jáde lọ́kàn mi dẹ́rù bà mí.

Dáníẹ́lì 4

Dáníẹ́lì 4:1-11